An episode of the AWON ONA TI ESU (SHATANI) FI MAA NDARI ENIYAN SI ONA ANU podcast, hosted by Qomorudeen Yunus, titled "" was published on April 11, 2026 and runs 51 minutes.
April 11, 2026 ·51m · AWON ONA TI ESU (SHATANI) FI MAA NDARI ENIYAN SI ONA ANU
0:00 / 0:00
Similar Episodes
Ajosepo Laarin Awon Musulumi ati Awon ti Won Kiise Musulumi
Apr 11, 2026 ·51m
Lilo Sunna Laarin Aseju ati Aseeto Lodo Awon Odo
Apr 11, 2026 ·51m
Similar Podcasts
Adua ati Iranti Olohun ni ona ti o to - 2
Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
Olubanisoro tesiwaju pelu sise alaye awon asiko ti adua ma ngba, o si tun menuba awon nkan ti kii je ki adua gba, o wa se akotan ibanisoro re pelu awon nkan ti Yoruba ti ro po mo adua.
Adua ati Iranti Olohun ni ona ti o to - 1
Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
Ohun ti ibanisoro yi da le lori ni oro nipa adua, olubanisoro se alaye awon ohun ti a npe ni eko adua ti o tumo si awon nkan ti o maa nse okunfa gbigba adua.
Ajosepo Laarin Awon Musulumi ati Awon ti Won Kiise Musulumi
Qomorudeen Yunus
Waasi yi so nipa awon nkan kan, ninu won niyi: (1) Musulumi ni eni ti iwa daradara ti Islam pepe si ba han ni ara re. (2) Ninu ohun ti esin Islam pase re ni ki Musulumi maa se aponle gbogbo eniyan, eni ti o je Musulumi ati eni ti kiise Musulumi, ki o si maa dun won ninu.
Lilo Sunna Laarin Aseju ati Aseeto Lodo Awon Odo
Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro , Hamid Yusuf
Ibanisọrọ yii da lori sise aseju tabi aseeto ninu ẹsin eyi ti o wọpọ laarin awọn ọdọ, ti olubanisọrọ si jẹ ki a mọ awọn okunfa rẹ gẹgẹ bii: 1-Aini imọ ẹsin ti o kun to, 2-Agbọye odi lori ẹsin, 3-lilero aburu si awọn onimimọ, 4-Igbarata ẹsin, 5- Sisọ gbogbo nkan di Bidi’ah, 6- fifun ilẹ mọni nibiti igbalaye wa ki gbolohun pe meji nibẹ. Ni igbẹyin, olubanisọrọ jẹ ki a mọ wipe gbigba Sunnah mu nikan ni o le yọ wa nibi aseju tabi aseeto.