just now

Podcast Image

Ẹbọ sise: Itumọ rẹ ati Awọn Ipin rẹ

Description

Idanilẹkọ yi da lori wipe idakeji ẹbọ sise ni sise Ọlọhun Allah ni aaso tabi gbigba A ni okan soso pẹlu ẹri Alukuraani ati ẹgbawa hadisi.Alaye tẹsiwaju nipa itumọ ẹbọ sise pẹlu awọn ọna ti ẹbọ sise pin si.

Details

Language:

YO

Release Date:

01/22/2022 14:33:16

Authors:

Abdur Rahman Muhammadul Awwal

Genres:

religion

Share this podcast

Episodes

Loading episodes...

Similar Podcasts

Loading similar podcasts...

Reviews -

Comments (0) -