just now
Dokita Simoni Olawale Olatunji ni alase, atokun ati oludari Ile Ise Kòjómoónù. Ile Ise ti n k'omo l'ede Yoruba kaakiri gbogbo agbaye. Lori ikanni yi, gbogbo olugbo wa yoo maa je anfani eko ofe ni ede Yoruba. A n k'omo l'asa, orin, iwa, alo, ewa, isesi ati itan ile Yoruba. Oludasile ile ise yi ko fe ki omo kankan ko gbe tabi sonu s'ajo. Odidere kii gbe s'oko, Edumare Oba oke ko ni je ka gbe s'ajo o. Amin, ase, Edumare!
yo
08/20/2020 22:34:07
Dọ́kítà ṢÍmóǹì Ọlátúnjí
society
Comments (0) -