PODCAST · society
Ìkànni Kòjómoónù Pẹ̀lúu Dọ́kítà ṢÍmóǹì Ọlátúnjí
by Dọ́kítà ṢÍmóǹì Ọlátúnjí
Dokita Simoni Olawale Olatunji ni alase, atokun ati oludari Ile Ise Kòjómoónù. Ile Ise ti n k'omo l'ede Yoruba kaakiri gbogbo agbaye. Lori ikanni yi, gbogbo olugbo wa yoo maa je anfani eko ofe ni ede Yoruba. A n k'omo l'asa, orin, iwa, alo, ewa, isesi ati itan ile Yoruba. Oludasile ile ise yi ko fe ki omo kankan ko gbe tabi sonu s'ajo. Odidere kii gbe s'oko, Edumare Oba oke ko ni je ka gbe s'ajo o. Amin, ase, Edumare!
-
7
Yoruba News @ 4
A rejoinder of the Ilana Omo Oodua Press Release
-
6
Ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò Pẹ̀lu Ààre Yoòbá Dálààsì
Ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lu Ààre Yoòbá Dálààsì - Dọ́kítà ṢÍmóǹì Ọlátúnjí
-
5
Ikànni Kòjómonónu
Dokita Simoni Olawale Olatunji ni alase, atokun ati oludari Ile Ise Kojomoonu. Ile Ise ti n k'omo l'ede Yoruba kaakiri gbogbo agbaye. Lori ikanni yi, gbogbo olugbo wa yoo maa je anfani eko ofe ni ede Yoruba. A n k'omo l'asa, orin, iwa, alo, ewa, isesi ati itan ile Yoruba. Oludasile ile ise yi ko fe ki omo kankan ko gbe
-
4
Àkànse Orin Kòjómoónò

3
Àyokà: Àgbà Inàkí Àtí Itàn Pàtàki Lórí Àmí Odo
Itan n k'omo l'ogbon; itan n k'omo l'ede. Ni aye atiji, itan ni awon baba wa n fii n k'omo ni asa, ewa ati isenbaye ile Yoruba
-
2
Ètò Gbélégbó: Akànse Ètò Lórí Àrùn Kòrónà
Ijíròrò l'órí bí a se le y'àgò fun Àjàkale Àrùn Kòrónà
-
1
KOJOMOONU RADIO: Akànse Ètò Lórí Àrùn Kòrónà Lórí Ètò Ghélégbó
KOJOMOONU RADIO hosts Ogbomoso Dallas leaders on how to protect yourself and flatten the curve of the pandemic. The broadcast is purely in native Yoruba language in the background of bata drumbeat and omele.
No matches for "" in this podcast's transcripts.
No topics indexed yet for this podcast.
Loading reviews...
ABOUT THIS SHOW
Dokita Simoni Olawale Olatunji ni alase, atokun ati oludari Ile Ise Kòjómoónù. Ile Ise ti n k'omo l'ede Yoruba kaakiri gbogbo agbaye. Lori ikanni yi, gbogbo olugbo wa yoo maa je anfani eko ofe ni ede Yoruba. A n k'omo l'asa, orin, iwa, alo, ewa, isesi ati itan ile Yoruba. Oludasile ile ise yi ko fe ki omo kankan ko gbe tabi sonu s'ajo. Odidere kii gbe s'oko, Edumare Oba oke ko ni je ka gbe s'ajo o. Amin, ase, Edumare!
HOSTED BY
Dọ́kítà ṢÍmóǹì Ọlátúnjí
Loading similar podcasts...