Ojise Aanu
BookmarkRafiu Adisa Bello , Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi
Ojise Aanu is a religion podcast hosted by Rafiu Adisa Bello , Ishaaq bn Ahmad al Ilaalawi. It has 6 episodes, with the latest published February 2014.
1- Oro lori koko ohun ti Olohun fi ran ojise Re Muhammad, iranse ni o je si gbogbo aye patapata.2- Pelu bi o ti je wipe awon osebo fi inira kan ojise Olohun ni ilu Makka sibe sibe o tun fi aanu bawon lo ti ko si fi ibi san ibi.3- Apejuwe lori aanu ti ojise Olohun ni fun awon eranko. Ikilo si waye lori fifi iya je awon eranko.4- Apejuwe nipa aanu re si awon ewe tabi awon omode.5- Apejuwe nipa aanu ojise Olohun si awon obinrin, oro si waye lori bi awon eniyan se maa nse abosi si won ni igba aimokan.6- Awon apejuwe nipa iteriba ati iwapele ojise Olohun. Bi o ti se ni aanu awon omoleyin re ti awon naa si ni ife si i.
religion ·YO ·6 episodes
Ojise Aanu - 6
Ojise Aanu - 1
Ojise Aanu - 2
Ojise Aanu - 3
Ojise Aanu - 4
Ojise Aanu - 5
Loading reviews...
Loading similar podcasts...