
All Episodes - Itọju Awọn Obi
[1] Asọtẹlẹ lati ọdọ Ọlọhun Allah ni sise daada si obi ẹni.[2] Alukuraani ati ẹgbawa hadisi sọ nipa pataki daada sise si awọn obi mejeeji.[3] Apẹẹrẹ oniran-nran daada ti eniyan le maa se si awọn obi rẹ.[4] Awọn ojuse ọmọ si obi pẹlu awọn apejuwe ifisisẹse rẹ lati ọdọ awọn sahabe Anọbi.[5] Awọn anfaani ti o wa nibi daada sise si awọn obi ẹni.Alaye nipa sise daada si awọn obi ẹni lẹyin ti wọn ti jade laye.
View Podcast Details